”””15/07/20.
Dahun awon ibeere wonyii lori itoju ayika ati ar eni.
- ko ohun elo meta ti o nilo lati fi toju ayika re
- ko idi pataki meji ti ijoba fi gbe eto gbale-gbata kale
- igba meloo ni o tona lati we loojo?
- ko idi meji ti ododo gbingbin fi se pataki si ayika wa
- pari owe yii: “imototo bori…………………..
Itoju Ara Ati Ayika
Itoju ara ni eto imototo ti a n lo lati fi se oge. Imototo bere lati inu ile eni kookan titi de ayika wa.
Orisiirisi ona ni a le gba lati fi se itoju ara wa.
- Eto imototo olorijori (Personal Hygiene)
- Wiwe deede, lojoojumo
- Fifo eyin wa ni ojoojumo
- Gige eekanna owo ati tie se lati bojumu
- Irun gige fun awon okunrin loorekoore
- Irun didi tabi kiko fun obinrin
- Fifo awon aso awotele wa lojoojumo
- Fifo owo saaju ati leyin ti a ba jeun tan
- Fifo abo ni kete leyin ounje
- Wiwo aso ti o mo toni-toni ti o sib o asiri ara wa a nigba gbogbo
- Titoju iho eti wa loorekoore
- Fifo eso ki a to je e
- Fifo owo mejeeji leyin igbonse
- Itoju Ile Ati Ayika
- Ile gbigba
- Oko sisan, ti o ba wa lagbegbe wa
- Gbingbin ododo ti o rewa si ayika
- Titoju oju agbara lati je ki omi san-an geere
- Didekun dida ile tabi idoti si oju agbara
- Didekun sise igbonse sibi atito
- Pipese ina monamona si adugbo fun eso ati lati dena awon amookunseka eda
Ewu ti o wa ninu aile-toju ara tabi ayika wa
- Nnkan itiju ni iwa obun je
- O le fa aisan si ago ara wa
- O le fa ajakale aarun
- O fi aye gba awon eranko oloro bii, ejo ati akeeke
23/06/20
E ku deede asiko yii o, a si ku afarada asiko yii, mo ni igbagbo pe e n pa gbogbo ofin imototo ti ijoba la kale fun mo. Oluwa yoo tubo maa pa wa mo o.
Idahun si awon ibeere ose to koja
- 3000
- 4000
- 5000
- 6000
- 7000
- 8000
- 9000
- 10000
- 11000
- 12000.
Itesiwaju onka Yoruba
Ko awon figo wonyii ni onka Yoruba:
- 13000
- 14000
- 15,000
- 15,500
- 16,000
- 16,500
- 17,000
- 17,500
- 18000
- 20000
17/06/20
Idahun si ibeere ose to koja
- 2000 –egbewa/egbaa
- 2100 –eedegbokanla
- 2200 –egbokanla
- 2300 –eedegbejila
- 2400 –egbejila
- 2500 –eedegbetala
- 2600 –egbetala
- 2700 –eedegberinla
- 2800 –egberinla
- 2900 –eedegbedogun
Itesiwaju onka
Ko awon onka wonyii ni figo
- Egbeedogun
- Egbaaji
- Egbeedogbon
- Egbaata
- Eedegbaarin
- Egbaarin
- Eedegbaarun-un
- Egbaarun-un
- Eedegbaafa
- Egbaafa
10/06/20.
Atunse si ise ose to koja
- Jagunjagun
- Gbomogbomo
- Wolewole
- Kolekole
- Sisesise
- Panapana
- Gbenagbena
- Omoomo
- Osoosu
- Odoodun
ONKA
Ko awon figo wonyii ni onka Yoruba
- 2000
- 2100
- 2200
- 2300
- 2400
- 2500
- 2600
- 2700
- 2800
- 2900.
03/06/20.
Mo fi asiko yii lu Adesina IbukunOluwa ni ogo enu, mo ri owo re, o ku ise o.
Eyi ni atunse si ise ose to koja
Afomo ibere | Oro-ise Adaduro | Oro-oruko Abajade. |
oni | ile | Onile |
i | jokoo | ijokoo |
ai | sun | aisun |
ai | rije | airije |
oni | isu | onisu |
on | taja | ontaja |
oni | aisan | alaisan |
a | kowe | akowe |
o | sise | osise |
1. Jagun
2. gbomo
3. wole
4 .kole
5. sise
6 .pana
7. gbena
8. omo
9. osu
10. odun
27/05/20.
E ku ojumo o eyin akekoo, a a jiire bi? Oluwa yoo maa pa wa mo o.
Wonyii ni awon idahun si awon ibeere ose to koja
- Ilu Eko
- Ilu Ibadan
- Lati se idupe ati idagbere
- Ilu Meka
- Oduduwa
- Bisoobu Samuel Ajayi Crowther
- Iro faweli meji lo wa
- (i) ede lilo maa n je ki tita ati rira rorun (ii) o maa n je ki a gbo ara wa ye (iii) o maa n je ki irepo wa
- Orisii meji
- Gbefe ati aigbefe.
Pin ihun awon oro wonyii si afomo ibere ati mofiimu adaduro
Afomo ibere | Oro-ise adaduro | Oro-oruko (Abajade) |
Oni | ile | |
Ijokoo | ||
Ai | Aisun | |
Airije | ||
Onisu | ||
Ontaja | ||
Alaisan | ||
Akowe | ||
Osise | ||
A | Peja |
20/05/20.
E ku deede asiko yii o eyin akekoo mi, a ku ifarada asiko yii o, Oluwa yoo maa ko wa yo o amin. Mo ni gbagbo pe e n se ara yin lojo(Staying stafe).
Wonyii ni awon ohun ti a o maa gbe yewo fun ti asiko yii.
Ibeere Oniruuru Lori Awon Akori Eko Ti A Ti Ko Koja.
- Ilu wo ni a n pe ni A-ro-mi-sa-legbe-legbe?
- Omo-a-je-oro-sun je oriki awon wo?
- Pataki ekun iyawo ni…….
- Ibo ni awon Yoruba ti se wa?
- ………… ni oruko baba-nla awon Yoruba
- Ta a ni o tumo Bibeli si ede Yoruba?
- Iro faweli meloo lo wa ninu ede Yoruba?
- Daruko meji lara iwulo ede
- Orisii leta meloo lo wa ninu ede Yoruba?
- Daruko won.
Jowo ri i daju pe o ko oruko ise (Yoruba) sinu akamo ti a pese fun idahun awon ibeere yii.
IRE O!
No Fields Found.